Orin Dafidi 18:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Mo fẹ́ràn rẹ, OLUWA, agbára mi.

2. OLUWA ni àpáta mi, ibi ààbò mi, ati olùgbàlà mi;Ọlọrun mi, àpáta mi, ninu ẹni tí ààbò mi wà.Òun ni asà mi, ìwo ìgbàlà mi ati ibi ìsásí mi.

3. Mo ké pe OLUWA, ẹni tí ìyìn yẹ,ó sì gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.

Orin Dafidi 18