Orin Dafidi 17:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní tèmi, èmi óo rí ojú rẹ nítorí òdodo mi,ìrísí rẹ yóo sì tẹ́ mi lọ́rùn nígbà tí mo bá jí.

Orin Dafidi 17

Orin Dafidi 17:13-15