Orin Dafidi 16:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi óo máa yin OLUWA, ẹni tí ó ń fún mi ní òye;ọkàn mi ó sì máa tọ́ mi sọ́nà ní òròòru.

Orin Dafidi 16

Orin Dafidi 16:1-11