Orin Dafidi 16:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ìwọ ni ìpín mi, ìwọ ni mo yàn;ìwọ ni ò ń jẹ́ kí ọ̀ràn mi fìdí múlẹ̀.

Orin Dafidi 16

Orin Dafidi 16:1-10