Orin Dafidi 148:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ yin OLUWA!Ẹ yin OLUWA, ẹ̀yin ẹ̀dá ọ̀run,ẹ yìn ín lókè ọ̀run.

2. Ẹ yìn ín, gbogbo ẹ̀yin angẹli rẹ̀;ẹ yìn ín, gbogbo ẹ̀yin ọmọ ogun rẹ̀.

3. Ẹ yìn ín, oòrùn ati òṣùpá;ẹ yìn ín, gbogbo ẹ̀yin ìràwọ̀ tí ń tàn.

Orin Dafidi 148