Orin Dafidi 146:9-10 BIBELI MIMỌ (BM)

9. OLUWA ni olùṣọ́ àwọn àlejò,òun ni alátìlẹ́yìn àwọn opó ati aláìníbaba,ṣugbọn a máa da ète àwọn eniyan burúkú rú.

10. OLUWA yóo jọba títí lae,Sioni, Ọlọrun rẹ yóo jọba láti ìran dé ìran.Ẹ yin OLUWA.

Orin Dafidi 146