Orin Dafidi 146:9 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ni olùṣọ́ àwọn àlejò,òun ni alátìlẹ́yìn àwọn opó ati aláìníbaba,ṣugbọn a máa da ète àwọn eniyan burúkú rú.

Orin Dafidi 146

Orin Dafidi 146:5-10