Orin Dafidi 146:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí ó fi Ọlọrun Jakọbu ṣe olùrànlọ́wọ́ rẹ̀,tí ó gbójú lé OLUWA, Ọlọrun rẹ̀.

Orin Dafidi 146

Orin Dafidi 146:4-10