Orin Dafidi 146:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ̀mí wọn bá ti bọ́, wọn á pada di erùpẹ̀,ní ọjọ́ náà sì ni èrò inú wọn óo di ègbé.

Orin Dafidi 146

Orin Dafidi 146:3-9