Orin Dafidi 145:19-21 BIBELI MIMỌ (BM)

19. Ó ń tẹ́ ìfẹ́ àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ̀ lọ́rùn;ó ń gbọ́ igbe wọn, ó sì ń gbà wọ́n.

20. OLUWA dá gbogbo àwọn tí ó fẹ́ ẹ sí,ṣugbọn yóo pa gbogbo àwọn eniyan burúkú run.

21. Ẹnu mi yóo máa sọ̀rọ̀ ìyìn OLUWA;kí gbogbo ẹ̀dá máa yin orúkọ rẹ̀ lae ati laelae.

Orin Dafidi 145