Orin Dafidi 144:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ayọ̀ ń bẹ fún orílẹ̀-èdè tí ó ní irú ibukun yìí;ayọ̀ ń bẹ fún orílẹ̀-èdè tí OLUWA jẹ́ Ọlọrun wọn.

Orin Dafidi 144

Orin Dafidi 144:6-15