Orin Dafidi 145:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Èmi óo gbé ọ ga, Ọlọrun mi, Ọba mi,n óo máa yin orúkọ rẹ lae ati laelae.

2. Lojoojumọ ni n óo máa yìn ọ́,tí n óo máa yin orúkọ rẹ lae ati laelae.

3. OLUWA tóbi, ìyìn sì yẹ ẹ́ lọpọlọpọ;àwámárìídìí ni títóbi rẹ̀.

Orin Dafidi 145