Orin Dafidi 144:14-15 BIBELI MIMỌ (BM)

14. Kí àwọn mààlúù wa lóyún,kí wọ́n má rọ́nú, kí wọ́n má bí òkúmọ;kí ó má sí ariwo àjálù ní ìgboro wa.

15. Ayọ̀ ń bẹ fún orílẹ̀-èdè tí ó ní irú ibukun yìí;ayọ̀ ń bẹ fún orílẹ̀-èdè tí OLUWA jẹ́ Ọlọrun wọn.

Orin Dafidi 144