Orin Dafidi 143:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo na ọwọ́ sí ọ fún ìrànlọ́wọ́;bí òùngbẹ omi í tií gbẹ ilẹ̀ gbígbẹ,bẹ́ẹ̀ ni òùngbẹ rẹ ń gbẹ ọkàn mi.

Orin Dafidi 143

Orin Dafidi 143:5-10