Orin Dafidi 143:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ranti ìgbà àtijọ́,mo ṣe àṣàrò lórí gbogbo ohun tí o ti ṣe,mo sì ronú lórí àwọn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.

Orin Dafidi 143

Orin Dafidi 143:2-10