Orin Dafidi 143:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Má dá èmi ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ lẹ́jọ́,nítorí pé kò sí ẹ̀dá alààyè tí ẹjọ́ rẹ̀ lè tọ́ níwájú rẹ.

Orin Dafidi 143

Orin Dafidi 143:1-11