Orin Dafidi 143:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, gbọ́ adura mi;fetí sí ẹ̀bẹ̀ mi!Dá mi lóhùn ninu òtítọ́ ati òdodo rẹ.

Orin Dafidi 143

Orin Dafidi 143:1-3