Orin Dafidi 142:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo wo ẹ̀gbẹ́ ọ̀tún mi yíká,mo rí i pé kò sí ẹni tí ó náání mi;kò sí ààbò fún mi,ẹnikẹ́ni kò sì bìkítà fún mi.

Orin Dafidi 142

Orin Dafidi 142:1-7