Orin Dafidi 142:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọkàn mi rẹ̀wẹ̀sì,ó mọ ọ̀nà tí mo lè gbà.Wọ́n ti dẹ tàkúté sílẹ̀ fún miní ọ̀nà tí mò ń rìn.

Orin Dafidi 142

Orin Dafidi 142:1-7