Orin Dafidi 141:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA, mo ké pè ọ́, tètè wá dá mi lóhùn,tẹ́tí sí ohùn mi nígbà tí mo bá ń ké pè ọ́.

2. Jẹ́ kí adura mi wá sí ọ̀dọ̀ rẹ bíi turari,sì jẹ́ kí ọwọ́ adura tí mo gbé sókè dàbí ẹbọ àṣáálẹ́.

3. OLUWA, fi ìjánu sí mi ní ẹnu,sì ṣe aṣọ́nà ètè mi.

Orin Dafidi 141