Orin Dafidi 141:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí adura mi wá sí ọ̀dọ̀ rẹ bíi turari,sì jẹ́ kí ọwọ́ adura tí mo gbé sókè dàbí ẹbọ àṣáálẹ́.

Orin Dafidi 141

Orin Dafidi 141:1-3