Orin Dafidi 14:5-7 BIBELI MIMỌ (BM)

5. Níbẹ̀ ni a óo ti dẹ́rù bà wọ́n gidigidi,nítorí Ọlọrun ń bẹ pẹlu àwọn olódodo.

6. Ẹ̀yin ń fẹ́ da ètò aláìní rú,ṣugbọn OLUWA ni ààbò rẹ̀.

7. Ìbá ti dára tó kí ìgbàlà Israẹli ti Sioni wá!Nígbà tí OLUWA bá dá ire àwọn eniyan rẹ̀ pada,Jakọbu yóo yọ̀, inú Israẹli yóo sì dùn.

Orin Dafidi 14