Orin Dafidi 139:10-13 BIBELI MIMỌ (BM)

10. níbẹ̀ gan-an, ọwọ́ rẹ ni yóo máa tọ́ mi,tí ọwọ́ ọ̀tún rẹ yóo sì dì mí mú.

11. Bí mo bá wí pé kí kìkì òkùnkùn bò mí mọ́lẹ̀,kí ọ̀sán di òru fún mi,

12. òkùnkùn gan-an kò ṣú jù fún ọ;òru mọ́lẹ̀ bí ọ̀sán;lójú rẹ, ìmọ́lẹ̀ kò yàtọ̀ sí òkùnkùn.

13. Nítorí ìwọ ni o dá inú mi,ìwọ ni o sọ mí di odidi ní inú ìyá mi.

Orin Dafidi 139