Orin Dafidi 139:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA, o ti yẹ̀ mí wò, o sì mọ̀ mí.

2. O mọ ìgbà tí mo jókòó, ati ìgbà tí mo dìde;o mọ èrò ọkàn mi láti òkèèrè réré.

3. O yẹ ìrìn ẹsẹ̀ mi ati àbọ̀sinmi mi wò;gbogbo ọ̀nà mi ni o sì mọ̀.

Orin Dafidi 139