Orin Dafidi 132:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí àwọn alufaa rẹ wọ ẹ̀wù òdodo,kí àwọn eniyan mímọ́ rẹ sì máa kọrin ayọ̀.

Orin Dafidi 132

Orin Dafidi 132:3-12