Orin Dafidi 132:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí àwọn ọmọ rẹ bá pa majẹmu mi mọ́,tí wọ́n sì tẹ̀lé ìlànà tí n óo fi lélẹ̀ fún wọn,àwọn ọmọ tiwọn náà óo jókòó lórí ìtẹ́ rẹ títí lae.”

Orin Dafidi 132

Orin Dafidi 132:10-18