Orin Dafidi 130:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ ní ìrètí ninu OLUWA!Nítorí pé ní ìkáwọ́ rẹ̀ ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ wà,ní ìkáwọ́ rẹ̀ sì ni ìràpadà kíkún wà.

Orin Dafidi 130

Orin Dafidi 130:2-8