Orin Dafidi 130:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Mò ń retí rẹ, OLUWA,ju bí àwọn aṣọ́de ti máa ń retí kí ilẹ̀ mọ́ lọ,àní, ju bí àwọn aṣọ́de, ti máa ń retí pé kí ilẹ̀ mọ́.

Orin Dafidi 130

Orin Dafidi 130:1-8