Orin Dafidi 126:4-6 BIBELI MIMỌ (BM)

4. Dá ire wa pada, OLUWA,bí ìṣàn omi ní ipadò aṣálẹ̀ Nẹgẹbu.

5. Àwọn tí ń fọ́n irúgbìn pẹlu omi lójú,jẹ́ kí wọn kórè rẹ̀ tayọ̀tayọ̀.

6. Ẹni tí ń gbé irúgbìn lọ sí oko tẹkúntẹkún,yóo ru ìtí ọkà pada sílé tayọ̀tayọ̀.

Orin Dafidi 126