Orin Dafidi 125:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí òkè ńlá ti yí Jerusalẹmu ká,bẹ́ẹ̀ ni OLUWA yí àwọn eniyan rẹ̀ ká,láti ìsinsìnyìí lọ ati títí lae.

Orin Dafidi 125

Orin Dafidi 125:1-5