Orin Dafidi 120:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) OLUWA ni mo ké pè, nígbà tí mo wà ninu ìpọ́njú,ó sì dá mi lóhùn. OLUWA, gbà mí lọ́wọ́ àwọn