Orin Dafidi 117:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ tóbi sí wa,òtítọ́ rẹ̀ sì wà títí laelae.Ẹ máa yin OLUWA.

Orin Dafidi 117

Orin Dafidi 117:1-2