Orin Dafidi 114:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin òkè ńlá, kí ló dé tí ẹ fi fò bí àgbò?Ẹ̀yin òkè kéékèèké, kí ló ṣẹlẹ̀ tí ẹ fi fò bí ọmọ aguntan?

Orin Dafidi 114

Orin Dafidi 114:3-8