Orin Dafidi 111:9-10 BIBELI MIMỌ (BM)

9. Ó ṣètò ìràpadà fún àwọn eniyan rẹ̀,ó fi ìdí majẹmu rẹ̀ múlẹ̀ títí lae,mímọ́ ni orúkọ rẹ̀, ó sì lọ́wọ̀.

10. Ìbẹ̀rù OLUWA ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n,gbogbo àwọn tí ó bá ń tẹ̀lé ìlànà rẹ̀, á máa ní ìmọ̀ pípé.Títí lae ni ìyìn rẹ̀.

Orin Dafidi 111