Orin Dafidi 111:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣètò ìràpadà fún àwọn eniyan rẹ̀,ó fi ìdí majẹmu rẹ̀ múlẹ̀ títí lae,mímọ́ ni orúkọ rẹ̀, ó sì lọ́wọ̀.

Orin Dafidi 111

Orin Dafidi 111:7-10