2. ẹ wo àwọn eniyan burúkú bí wọ́n ti kẹ́ ọfà;wọ́n fa ọrun;wọ́n sì fi òkùnkùn bojú láti ta olódodo lọ́fà.
3. Nígbà tí ìpìlẹ̀ bá bàjẹ́,kí ni olódodo lè ṣe?”
4. OLUWA ń bẹ ninu tẹmpili mímọ́ rẹ̀,ìtẹ́ rẹ̀ wà lọ́run;OLUWA ń kíyèsí àwọn ọmọ eniyan,ó sì ń yẹ̀ wọ́n wò.