Orin Dafidi 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ń bẹ ninu tẹmpili mímọ́ rẹ̀,ìtẹ́ rẹ̀ wà lọ́run;OLUWA ń kíyèsí àwọn ọmọ eniyan,ó sì ń yẹ̀ wọ́n wò.

Orin Dafidi 11

Orin Dafidi 11:2-7