Orin Dafidi 108:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jí ẹ̀yin ohun èlò ìkọrin ati hapu!Èmi fúnra mi náà yóo jí ní òwúrọ̀ kutukutu,

Orin Dafidi 108

Orin Dafidi 108:1-10