Orin Dafidi 108:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn mi dúró ṣinṣin, Ọlọrunọkàn mi dúró ṣinṣin.N óo kọrin, n óo sì máa yìn ọ́.Jí, ìwọ ọkàn mi!

Orin Dafidi 108

Orin Dafidi 108:1-10