Orin Dafidi 107:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun,nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.

Orin Dafidi 107

Orin Dafidi 107:1-5