Orin Dafidi 106:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbà wá, OLUWA, Ọlọrun wa,kí o sì kó wa kúrò láàrin àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn,kí á lè máa fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ,kí á sì lè máa ṣògo ninu ìyìn rẹ.

Orin Dafidi 106

Orin Dafidi 106:42-47