Orin Dafidi 105:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, ẹ pe orúkọ rẹ̀,ẹ fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn ní gbogbo orílẹ̀-èdè.

Orin Dafidi 105

Orin Dafidi 105:1-2