Orin Dafidi 104:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ parẹ́ lórí ilẹ̀ ayé,kí àwọn eniyan burúkú má sí mọ́.Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi!Yin OLUWA!

Orin Dafidi 104

Orin Dafidi 104:31-35