Orin Dafidi 104:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wo òkun bí ó ti tóbi tí ó sì fẹ̀,ó kún fún ọ̀kẹ́ àìmọye ẹ̀dá,nǹkan abẹ̀mí kéékèèké ati ńláńlá.

Orin Dafidi 104

Orin Dafidi 104:16-34