Orin Dafidi 104:24 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ìyanu ni iṣẹ́ ọwọ́ rẹ!Ọgbọ́n ni o fi dá gbogbo wọn.Ayé kún fún àwọn ẹ̀dá rẹ.

Orin Dafidi 104

Orin Dafidi 104:19-33