Orin Dafidi 103:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó ń fi ohun dáradára tẹ́ ọ lọ́rùn,tí ó fi ń sọ agbára ìgbà èwe rẹ dọ̀tun bíi ti idì.

Orin Dafidi 103

Orin Dafidi 103:1-10