Orin Dafidi 103:4 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹni tí ó ń yọ ẹ̀mí rẹ kúrò ninu ọ̀fìn,tí ó fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ ati àánú dé ọ ládé.

Orin Dafidi 103

Orin Dafidi 103:2-9