Orin Dafidi 102:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí àwọn òkúta rẹ̀ ṣe iyebíye lójú àwọn iranṣẹ rẹ,àánú rẹ̀ sì ṣeni bí ó tilẹ̀ ti wó dà sinu erùpẹ̀.

Orin Dafidi 102

Orin Dafidi 102:13-20