Orin Dafidi 102:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ óo dìde, o óo sì ṣàánú Sioni,nítorí ó tó àkókò láti fi ojú àánú wò ó.Àkókò tí o dá tó.

Orin Dafidi 102

Orin Dafidi 102:3-14