Orin Dafidi 102:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Gbọ́ adura mi, OLUWA;kí o sì jẹ́ kí igbe mi dé ọ̀dọ̀ rẹ.

2. Má yọwọ́ lọ́ràn mi lọ́jọ́ ìṣòro!Dẹtí sí adura mi;kí o sì tètè dá mi lóhùn nígbà tí mo bá ké pè ọ́.

Orin Dafidi 102